IYA GIDI NI MO FẸ K'IJỌBA FI JẸ ENI TO JI ỌMỌ MI GBE LỌ SI LIBYA- AFỌLABI

Поделиться
HTML-код
  • Опубликовано: 12 сен 2024
  • We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...

Комментарии • 12

  • @user-pu3sh4ml6m
    @user-pu3sh4ml6m 22 дня назад

    This woman really tried , Locating her where about going from one place to the other and even Contacted the Police , Kudos to her She s a Nice mother

  • @azeezfatima3408
    @azeezfatima3408 3 месяца назад +1

    Omowa oni sonu

  • @olumuyiwakusimo2184
    @olumuyiwakusimo2184 3 месяца назад +1

    Aiye oni fi Omo dawa lamu. Moki Mama yi gidi gidi, eku oro Omo. Isu omo ajina fun gbogbo eyin abiyamo rere o amin 🙏. Mobayin yo wipe Olorun se Omo na ni riri.

  • @rasakwaliyu7759
    @rasakwaliyu7759 3 месяца назад +1

    Ẹ̀seun fun part 2 ọrọ naa

  • @user-vq2mr3el2g
    @user-vq2mr3el2g 3 месяца назад +1

    Omo buruku lomo yen, eyan buruku de ni Ajinigbe yen. Ki won so si Ewon gbere

  • @anneemitomo6134
    @anneemitomo6134 3 месяца назад +5

    E ma ran awon omobirin da rin lo si school tabi nikan jade, awon odaju obirin ati okunrin to nje ounje ese,, to nnawo ese, ika
    E si jeki awon omo wa je ore wa ki nwon ma so ohun gbogbo ti enikeni ba ba won so fun wa, ki nwon ma fi ohunkohun pamo fun wa, nwon ti lo ogun fun, nwon ko ni jeki o gba call, nwon ma ngba phone lowo won awon agents of devils 😈

  • @princebello807
    @princebello807 3 месяца назад

    Ogaaa oo

  • @ojoabuletagba6561
    @ojoabuletagba6561 3 месяца назад

    Olorun oseun oo

  • @ibaileibaomo7660
    @ibaileibaomo7660 3 месяца назад

    Ore niwon.

  • @saheedadewale5901
    @saheedadewale5901 3 месяца назад

    Kin won ma fi obirin ajimogbe yen sile ooo

  • @adecrown4413
    @adecrown4413 3 месяца назад

    Omo re je alaileko.

  • @user-pu3sh4ml6m
    @user-pu3sh4ml6m 22 дня назад

    This woman in Charge of Caring for this girl is a nice woman but the girl is a bad girl